-
Sáàmù 78:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Níkẹyìn, ó pa gbogbo àkọ́bí Íjíbítì,+
Ìbẹ̀rẹ̀ agbára ìbímọ wọn nínú àwọn àgọ́ Hámù.
-
-
Sáàmù 105:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Lẹ́yìn náà, ó pa gbogbo àkọ́bí tó wà ní ilẹ̀ wọn,+
Ìbẹ̀rẹ̀ agbára ìbímọ wọn.
-