-
Ẹ́kísódù 10:28, 29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Fáráò sọ fún Mósè pé: “Kúrò níwájú mi! O ò gbọ́dọ̀ tún fi ojú kàn mí mọ́, torí ọjọ́ tí o bá fi ojú kàn mí ni wàá kú.” 29 Mósè wá fèsì pé: “Bí o ṣe sọ, mi ò ní fojú kàn ọ́ mọ́.”
-