-
Ẹ́kísódù 10:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àwọn ìránṣẹ́ Fáráò wá sọ fún un pé: “Ìgbà wo ni ọkùnrin yìí fẹ́ ṣèyí dà, tí yóò máa kó wa sínú ewu?* Jẹ́ kí àwọn èèyàn náà máa lọ kí wọ́n lè sin Jèhófà Ọlọ́run wọn. Ṣé o ò rí i pé Íjíbítì ti run tán ni?”
-