Gálátíà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Síwájú sí i, mo sọ èyí pé: Òfin tó dé ní ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ọgbọ̀n (430) ọdún lẹ́yìn náà+ kò fagi lé májẹ̀mú tí Ọlọ́run ti dá, tó fi máa fòpin sí ìlérí náà.
17 Síwájú sí i, mo sọ èyí pé: Òfin tó dé ní ọgọ́rùn-ún mẹ́rin ó lé ọgbọ̀n (430) ọdún lẹ́yìn náà+ kò fagi lé májẹ̀mú tí Ọlọ́run ti dá, tó fi máa fòpin sí ìlérí náà.