Sáàmù 105:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ó na àwọsánmà* bo àwọn èèyàn rẹ̀,+Ó sì pèsè iná láti fún wọn ní ìmọ́lẹ̀ ní òru.+ 1 Kọ́ríńtì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+
10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+