1 Kọ́ríńtì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+ Hébérù 11:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ìgbàgbọ́ mú kí wọ́n la Òkun Pupa kọjá bíi pé ilẹ̀ gbígbẹ ni,+ àmọ́ nígbà tí àwọn ará Íjíbítì dán an wò, omi gbé wọn mì.+
10 Ní báyìí, ẹ̀yin ará, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé gbogbo àwọn baba ńlá wa wà lábẹ́ ìkùukùu,*+ gbogbo wọn gba inú òkun kọjá,+
29 Ìgbàgbọ́ mú kí wọ́n la Òkun Pupa kọjá bíi pé ilẹ̀ gbígbẹ ni,+ àmọ́ nígbà tí àwọn ará Íjíbítì dán an wò, omi gbé wọn mì.+