Sáàmù 77:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọ̀nà rẹ gba inú òkun kọjá,+Ipa ọ̀nà rẹ sì gba inú omi púpọ̀ kọjá;Àmọ́ a kò lè rí ipa ẹsẹ̀ rẹ.