Sáàmù 83:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+ Sáàmù 148:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+
18 Kí àwọn èèyàn lè mọ̀ pé ìwọ, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jèhófà,+Ìwọ nìkan ṣoṣo ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé.+
13 Kí wọ́n máa yin orúkọ Jèhófà,Nítorí orúkọ rẹ̀ nìkan ṣoṣo ló ga kọjá ibi tó ṣeé dé.+ Iyì rẹ̀ ga ju ayé àti ọ̀run lọ.+