Ẹ́kísódù 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mo ti máa ń fara han Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù pé èmi ni Ọlọ́run Olódùmarè,+ àmọ́ ní ti orúkọ mi Jèhófà,+ mi ò jẹ́ kí wọ́n fi mọ̀ mí.+ Àìsáyà 42:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Èmi ni Jèhófà. Orúkọ mi nìyẹn;Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì,*Èmi kì í sì í fi ìyìn mi fún àwọn ère gbígbẹ́.+
3 Mo ti máa ń fara han Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù pé èmi ni Ọlọ́run Olódùmarè,+ àmọ́ ní ti orúkọ mi Jèhófà,+ mi ò jẹ́ kí wọ́n fi mọ̀ mí.+
8 Èmi ni Jèhófà. Orúkọ mi nìyẹn;Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì,*Èmi kì í sì í fi ìyìn mi fún àwọn ère gbígbẹ́.+