-
Ẹ́kísódù 14:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ló bá múra àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀, ó sì kó àwọn èèyàn rẹ̀ dání.+ 7 Ó yan ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) kẹ̀kẹ́ ẹṣin tó dáa, ó sì kó wọn dání pẹ̀lú gbogbo kẹ̀kẹ́ ẹṣin yòókù ní Íjíbítì, jagunjagun sì wà nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn.
-