Ẹ́kísódù 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Fáráò ò ní fetí sí yín,+ kí iṣẹ́ ìyanu mi lè pọ̀ sí i nílẹ̀ Íjíbítì.”+