Sáàmù 78:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Ó darí wọn láìséwu,Wọn ò sì bẹ̀rù ohunkóhun;+Òkun bo àwọn ọ̀tá wọn mọ́lẹ̀.+ Hébérù 11:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ìgbàgbọ́ mú kí wọ́n la Òkun Pupa kọjá bíi pé ilẹ̀ gbígbẹ ni,+ àmọ́ nígbà tí àwọn ará Íjíbítì dán an wò, omi gbé wọn mì.+
29 Ìgbàgbọ́ mú kí wọ́n la Òkun Pupa kọjá bíi pé ilẹ̀ gbígbẹ ni,+ àmọ́ nígbà tí àwọn ará Íjíbítì dán an wò, omi gbé wọn mì.+