-
Nọ́ńbà 22:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá gbéra, wọ́n sì pàgọ́ sí aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù, ní òdìkejì Jọ́dánì láti Jẹ́ríkò.+
-
-
Nọ́ńbà 22:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ẹ̀rù àwọn èèyàn náà ba Móábù gan-an, torí wọ́n pọ̀ rẹpẹtẹ; kódà jìnnìjìnnì bá Móábù torí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
-