-
Ẹ́kísódù 2:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àlùfáà Mídíánì+ ní ọmọbìnrin méje, àwọn ọmọ yìí wá fa omi, wọ́n sì pọnmi kún àwọn ọpọ́n ìmumi kí wọ́n lè fún agbo ẹran bàbá wọn lómi.
-