Sáàmù 80:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 O mú kí àjàrà+ kan kúrò ní Íjíbítì. O lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde, o sì gbin àjàrà náà.+