ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 7:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “Tí ẹ bá ń tẹ́tí sí àwọn ìdájọ́ yìí, tí ẹ̀ ń tẹ̀ lé wọn, tí ẹ sì ń pa wọ́n mọ́, Jèhófà Ọlọ́run yín máa pa májẹ̀mú tó bá àwọn baba ńlá yín dá mọ́, ó sì máa fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn bó ṣe ṣèlérí.

  • Diutarónómì 7:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Jèhófà máa mú gbogbo àìsàn kúrò lára rẹ; kò sì ní jẹ́ kí ìkankan nínú gbogbo àrùn burúkú tí o ti mọ̀ ní Íjíbítì ṣe ọ́.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, gbogbo àwọn tó kórìíra rẹ ló máa fi àrùn náà ṣe.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́