Mátíù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Fún wa ní oúnjẹ òòjọ́ wa lónìí;+ Mátíù 6:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Torí náà, ẹ má ṣàníyàn láé nípa ọ̀la,+ torí ọ̀la máa ní àwọn àníyàn tirẹ̀. Wàhálà ọjọ́ kọ̀ọ̀kan ti tó fún un.
34 Torí náà, ẹ má ṣàníyàn láé nípa ọ̀la,+ torí ọ̀la máa ní àwọn àníyàn tirẹ̀. Wàhálà ọjọ́ kọ̀ọ̀kan ti tó fún un.