Sáàmù 81:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 O pè mí nínú wàhálà tó bá ọ, mo sì gbà ọ́ sílẹ̀;+Mo dá ọ lóhùn láti ojú ọ̀run tó ń sán ààrá.*+ Mo dán ọ wò níbi omi Mẹ́ríbà.*+ (Sélà)
7 O pè mí nínú wàhálà tó bá ọ, mo sì gbà ọ́ sílẹ̀;+Mo dá ọ lóhùn láti ojú ọ̀run tó ń sán ààrá.*+ Mo dán ọ wò níbi omi Mẹ́ríbà.*+ (Sélà)