Jẹ́nẹ́sísì 36:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tímínà di wáhàrì* Élífásì ọmọ Ísọ̀. Nígbà tó yá, ó bí Ámálékì+ fún Élífásì. Àwọn ni ọmọ Ádà ìyàwó Ísọ̀.
12 Tímínà di wáhàrì* Élífásì ọmọ Ísọ̀. Nígbà tó yá, ó bí Ámálékì+ fún Élífásì. Àwọn ni ọmọ Ádà ìyàwó Ísọ̀.