Jóṣúà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jóṣúà gba gbogbo ìlú àwọn ọba yìí, ó sì fi idà ṣẹ́gun gbogbo ọba wọn.+ Ó pa wọ́n run,+ bí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.
12 Jóṣúà gba gbogbo ìlú àwọn ọba yìí, ó sì fi idà ṣẹ́gun gbogbo ọba wọn.+ Ó pa wọ́n run,+ bí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.