Ẹ́kísódù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tó yá, obìnrin náà bí ọmọkùnrin kan, Mósè sì sọ ọ́ ní Gẹ́ṣómù,*+ torí ó sọ pé, “Mo ti di àjèjì nílẹ̀ àjèjì.”+
22 Nígbà tó yá, obìnrin náà bí ọmọkùnrin kan, Mósè sì sọ ọ́ ní Gẹ́ṣómù,*+ torí ó sọ pé, “Mo ti di àjèjì nílẹ̀ àjèjì.”+