2 Nítorí náà, alábòójútó gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹni tí kò lẹ́gàn, tí kò ní ju ìyàwó kan lọ, tí kì í ṣe àṣejù, tó ní àròjinlẹ̀,+ tó wà létòlétò, tó ń ṣe aájò àlejò,+ tó kúnjú ìwọ̀n láti kọ́ni,+ 3 kì í ṣe ọ̀mùtí,+ kì í ṣe oníwà ipá, àmọ́ kó máa fòye báni lò,+ kì í ṣe oníjà,+ kì í ṣe ẹni tó fẹ́ràn owó,+