15 Torí náà, mo mú àwọn olórí ẹ̀yà yín, àwọn ọkùnrin tó jẹ́ ọlọ́gbọ́n, tí wọ́n sì ní ìrírí, mo yàn wọ́n ṣe olórí yín, olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún, olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún, olórí àràádọ́ta, olórí àwọn mẹ́wàá-mẹ́wàá àti àwọn aṣojú nínú àwọn ẹ̀yà yín.+
23 Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n yan àwọn alàgbà fún wọn nínú ìjọ kọ̀ọ̀kan,+ wọ́n gbàdúrà pẹ̀lú ààwẹ̀,+ wọ́n sì fà wọ́n lé Jèhófà* lọ́wọ́, ẹni tí wọ́n ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀.