Ìṣe 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àmọ́ lẹ́yìn tí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà ti bá wọn jiyàn díẹ̀, tí wọ́n sì jọ ṣe awuyewuye, àwọn ará ṣètò pé kí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà pẹ̀lú àwọn míì lọ sọ́dọ̀ àwọn àpọ́sítélì àti àwọn alàgbà ní Jerúsálẹ́mù+ lórí ọ̀rọ̀* yìí.
2 Àmọ́ lẹ́yìn tí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà ti bá wọn jiyàn díẹ̀, tí wọ́n sì jọ ṣe awuyewuye, àwọn ará ṣètò pé kí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà pẹ̀lú àwọn míì lọ sọ́dọ̀ àwọn àpọ́sítélì àti àwọn alàgbà ní Jerúsálẹ́mù+ lórí ọ̀rọ̀* yìí.