Ìṣe 7:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ẹni yìí wà lára ìjọ tó wà ní aginjù, ó wà pẹ̀lú áńgẹ́lì+ tó bá a sọ̀rọ̀+ lórí Òkè Sínáì pẹ̀lú àwọn baba ńlá wa, ó sì gba àwọn ọ̀rọ̀ ìkéde mímọ́ tó jẹ́ ààyè láti fún wa.+
38 Ẹni yìí wà lára ìjọ tó wà ní aginjù, ó wà pẹ̀lú áńgẹ́lì+ tó bá a sọ̀rọ̀+ lórí Òkè Sínáì pẹ̀lú àwọn baba ńlá wa, ó sì gba àwọn ọ̀rọ̀ ìkéde mímọ́ tó jẹ́ ààyè láti fún wa.+