Diutarónómì 32:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Bí ẹyẹ idì ṣe ń ru ìtẹ́ rẹ̀ sókè,Tó ń rá bàbà lórí àwọn ọmọ rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gúnyẹ̀ẹ́,Tó ń na àwọn ìyẹ́ rẹ̀ jáde láti fi gbé wọn,Tó ń gbé wọn sórí apá+ rẹ̀, 12 Jèhófà nìkan ló ń darí rẹ̀;*+Kò sí ọlọ́run àjèjì kankan pẹ̀lú rẹ̀.+ Àìsáyà 63:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nínú gbogbo ìdààmú wọn, ìdààmú bá òun náà.+ Ìránṣẹ́ òun fúnra rẹ̀* sì gbà wọ́n là.+ Ó tún wọn rà nínú ìfẹ́ rẹ̀ àti ìyọ́nú rẹ̀,+Ó gbé wọn sókè, ó sì rù wọ́n ní gbogbo ìgbà àtijọ́.+
11 Bí ẹyẹ idì ṣe ń ru ìtẹ́ rẹ̀ sókè,Tó ń rá bàbà lórí àwọn ọmọ rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ gúnyẹ̀ẹ́,Tó ń na àwọn ìyẹ́ rẹ̀ jáde láti fi gbé wọn,Tó ń gbé wọn sórí apá+ rẹ̀, 12 Jèhófà nìkan ló ń darí rẹ̀;*+Kò sí ọlọ́run àjèjì kankan pẹ̀lú rẹ̀.+
9 Nínú gbogbo ìdààmú wọn, ìdààmú bá òun náà.+ Ìránṣẹ́ òun fúnra rẹ̀* sì gbà wọ́n là.+ Ó tún wọn rà nínú ìfẹ́ rẹ̀ àti ìyọ́nú rẹ̀,+Ó gbé wọn sókè, ó sì rù wọ́n ní gbogbo ìgbà àtijọ́.+