Diutarónómì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wò ó, Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló ni ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run,* pẹ̀lú ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.+
14 Wò ó, Jèhófà Ọlọ́run rẹ ló ni ọ̀run, àní ọ̀run àwọn ọ̀run,* pẹ̀lú ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.+