Nọ́ńbà 16:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nígbà tí Kórà kó àwọn tó ń tì í lẹ́yìn,+ tí wọ́n jọ ń ta kò wọ́n jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà fara han gbogbo àpéjọ+ náà. Nọ́ńbà 16:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Iná sì wá látọ̀dọ̀ Jèhófà,+ ó jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin tó ń sun tùràrí+ run.
19 Nígbà tí Kórà kó àwọn tó ń tì í lẹ́yìn,+ tí wọ́n jọ ń ta kò wọ́n jọ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà fara han gbogbo àpéjọ+ náà.