Léfítíkù 25:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “‘Tí arákùnrin rẹ tó ń gbé nítòsí bá di aláìní, tó sì ní láti ta ara rẹ̀ fún ọ,+ má fipá mú un ṣe ẹrú.+ 40 Bí alágbàṣe,+ bí àlejò ni kí o ṣe mú un. Kó máa sìn ọ́ títí di ọdún Júbílì.
39 “‘Tí arákùnrin rẹ tó ń gbé nítòsí bá di aláìní, tó sì ní láti ta ara rẹ̀ fún ọ,+ má fipá mú un ṣe ẹrú.+ 40 Bí alágbàṣe,+ bí àlejò ni kí o ṣe mú un. Kó máa sìn ọ́ títí di ọdún Júbílì.