Diutarónómì 24:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ gba ọlọ tàbí ọmọ ọlọ láti fi ṣe ìdúró,*+ torí ohun tó ń gbé ẹ̀mí onítọ̀hún ró* ló fẹ́ gbà láti fi ṣe ìdúró yẹn.
6 “Ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ gba ọlọ tàbí ọmọ ọlọ láti fi ṣe ìdúró,*+ torí ohun tó ń gbé ẹ̀mí onítọ̀hún ró* ló fẹ́ gbà láti fi ṣe ìdúró yẹn.