-
Léfítíkù 22:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 “Tí màlúù, àgbò tàbí ewúrẹ́ bá bímọ, ọjọ́ méje+ ni kí ọmọ náà fi wà pẹ̀lú ìyá rẹ̀, àmọ́ láti ọjọ́ kẹjọ sókè, tí wọ́n bá fi ṣe ọrẹ, ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, ó máa rí ìtẹ́wọ́gbà.
-