Sáàmù 135:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà, orúkọ rẹ wà títí láé. Jèhófà, òkìkí rẹ yóò máa kàn* láti ìran dé ìran.+