ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 22:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Tí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tàbí akọ màlúù arákùnrin rẹ tó ṣubú lójú ọ̀nà, má mọ̀ọ́mọ̀ mójú kúrò. Rí i dájú pé o bá a gbé ẹran náà dìde.+

  • Lúùkù 6:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 “Àmọ́ mò ń sọ fún ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fetí sílẹ̀ pé: Ẹ máa nífẹ̀ẹ́ àwọn ọ̀tá yín, kí ẹ máa ṣe rere sí àwọn tó kórìíra yín,+

  • Róòmù 12:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Má ṣe jẹ́ kí ibi ṣẹ́gun rẹ, àmọ́ máa fi ire ṣẹ́gun ibi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́