Nọ́ńbà 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà tún sọ fún Áárónì pé: “Èmi fúnra mi fi gbogbo ọrẹ tí wọ́n bá ṣe fún mi+ sí ìkáwọ́ rẹ. Mo ti fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ lára gbogbo ohun mímọ́ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá fi ṣe ọrẹ, kó jẹ́ ìpín+ yín títí lọ. Nọ́ńbà 18:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Mo fún ọ+ ní gbogbo òróró tó dáa jù àti gbogbo wáìnì tuntun tó dáa jù àti ọkà, àkọ́so+ wọn, èyí tí wọ́n fún Jèhófà. 1 Kọ́ríńtì 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ ní báyìí, a ti gbé Kristi dìde kúrò nínú ikú, àkọ́so nínú àwọn tó ti sùn nínú ikú.+
8 Jèhófà tún sọ fún Áárónì pé: “Èmi fúnra mi fi gbogbo ọrẹ tí wọ́n bá ṣe fún mi+ sí ìkáwọ́ rẹ. Mo ti fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ lára gbogbo ohun mímọ́ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá fi ṣe ọrẹ, kó jẹ́ ìpín+ yín títí lọ.
12 “Mo fún ọ+ ní gbogbo òróró tó dáa jù àti gbogbo wáìnì tuntun tó dáa jù àti ọkà, àkọ́so+ wọn, èyí tí wọ́n fún Jèhófà.