Diutarónómì 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa mú kí wọ́n rẹ̀wẹ̀sì* títí àwọn tó ṣẹ́ kù+ àti àwọn tó ń fara pa mọ́ fún ọ fi máa pa run. Jóṣúà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà tí a gbọ́ nípa rẹ̀, ọkàn wa domi,* kò sì sẹ́ni tó ní ìgboyà* mọ́ nítorí yín, torí Jèhófà Ọlọ́run yín ni Ọlọ́run lókè ọ̀run àti lórí ilẹ̀ ayé.+
20 Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa mú kí wọ́n rẹ̀wẹ̀sì* títí àwọn tó ṣẹ́ kù+ àti àwọn tó ń fara pa mọ́ fún ọ fi máa pa run.
11 Nígbà tí a gbọ́ nípa rẹ̀, ọkàn wa domi,* kò sì sẹ́ni tó ní ìgboyà* mọ́ nítorí yín, torí Jèhófà Ọlọ́run yín ni Ọlọ́run lókè ọ̀run àti lórí ilẹ̀ ayé.+