Jóṣúà 24:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘Lẹ́yìn náà, ẹ sọdá Jọ́dánì,+ ẹ sì dé Jẹ́ríkò.+ Àwọn olórí* ìlú Jẹ́ríkò, àwọn Ámórì, àwọn Pérísì, àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì bá yín jà, àmọ́ mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.+
11 “‘Lẹ́yìn náà, ẹ sọdá Jọ́dánì,+ ẹ sì dé Jẹ́ríkò.+ Àwọn olórí* ìlú Jẹ́ríkò, àwọn Ámórì, àwọn Pérísì, àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì bá yín jà, àmọ́ mo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́.+