Diutarónómì 5:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Àwọn àṣẹ* yìí ni Jèhófà pa fún gbogbo ìjọ yín lórí òkè náà, látinú iná àti ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà+ pẹ̀lú ohùn tó dún ketekete, kò sì fi ohunkóhun kún un; ó wá kọ wọ́n sórí wàláà òkúta méjì, ó sì kó o fún mi.+
22 “Àwọn àṣẹ* yìí ni Jèhófà pa fún gbogbo ìjọ yín lórí òkè náà, látinú iná àti ìkùukùu* àti ìṣúdùdù tó kàmàmà+ pẹ̀lú ohùn tó dún ketekete, kò sì fi ohunkóhun kún un; ó wá kọ wọ́n sórí wàláà òkúta méjì, ó sì kó o fún mi.+