Ẹ́kísódù 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jóṣúà ṣe ohun tí Mósè sọ fún un,+ ó sì bá àwọn ọmọ Ámálékì jà. Mósè, Áárónì àti Húrì + wá gun òkè náà lọ.
10 Jóṣúà ṣe ohun tí Mósè sọ fún un,+ ó sì bá àwọn ọmọ Ámálékì jà. Mósè, Áárónì àti Húrì + wá gun òkè náà lọ.