9 Kò sí nǹkan míì nínú Àpótí náà àfi wàláà òkúta méjì+ tí Mósè kó síbẹ̀+ ní Hórébù, nígbà tí Jèhófà bá àwọn èèyàn Ísírẹ́lì dá májẹ̀mú+ bí wọ́n ṣe ń jáde bọ̀ láti ilẹ̀ Íjíbítì.+
4 Àwo tùràrí oníwúrà+ àti àpótí májẹ̀mú + tí wọ́n fi wúrà bò látòkè délẹ̀+ wà níbẹ̀, inú rẹ̀ ni ìṣà wúrà tí wọ́n kó mánà+ sí wà pẹ̀lú ọ̀pá Áárónì tó yọ òdòdó+ àti àwọn wàláà+ májẹ̀mú;