- 
	                        
            
            Hébérù 9:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Àwo tùràrí oníwúrà+ àti àpótí májẹ̀mú + tí wọ́n fi wúrà bò látòkè délẹ̀+ wà níbẹ̀, inú rẹ̀ ni ìṣà wúrà tí wọ́n kó mánà+ sí wà pẹ̀lú ọ̀pá Áárónì tó yọ òdòdó+ àti àwọn wàláà+ májẹ̀mú; 5 àwọn kérúbù ológo tí wọ́n ṣíji bo ìbòrí ìpẹ̀tù*+ sì wà lórí rẹ̀. Àmọ́ àkókò kọ́ nìyí láti máa sọ kúlẹ̀kúlẹ̀ àwọn nǹkan yìí. 
 
-