Ẹ́kísódù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àmọ́ Fáráò sọ pé: “Ta ni Jèhófà,+ tí màá fi gbọ́ràn sí i lẹ́nu pé kí n jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ?+ Mi ò mọ Jèhófà rárá, mi ò sì ní jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ.”+ Ẹ́kísódù 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bí Jèhófà ṣe jẹ́ kí ọkàn Fáráò ọba Íjíbítì le nìyẹn, ó sì ń lépa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àmọ́ ọkàn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì balẹ̀* bí wọ́n ṣe ń lọ.+ Róòmù 9:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí Ìwé Mímọ́ sọ fún Fáráò pé: “Ìdí tí mo fi jẹ́ kí o máa wà nìṣó ni pé: kí n lè fi agbára mi hàn nípasẹ̀ rẹ àti pé kí a lè ròyìn orúkọ mi ní gbogbo ayé.”+
2 Àmọ́ Fáráò sọ pé: “Ta ni Jèhófà,+ tí màá fi gbọ́ràn sí i lẹ́nu pé kí n jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ?+ Mi ò mọ Jèhófà rárá, mi ò sì ní jẹ́ kí Ísírẹ́lì lọ.”+
8 Bí Jèhófà ṣe jẹ́ kí ọkàn Fáráò ọba Íjíbítì le nìyẹn, ó sì ń lépa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àmọ́ ọkàn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì balẹ̀* bí wọ́n ṣe ń lọ.+
17 Nítorí Ìwé Mímọ́ sọ fún Fáráò pé: “Ìdí tí mo fi jẹ́ kí o máa wà nìṣó ni pé: kí n lè fi agbára mi hàn nípasẹ̀ rẹ àti pé kí a lè ròyìn orúkọ mi ní gbogbo ayé.”+