Nọ́ńbà 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí wọ́n ṣe ṣe ọ̀pá fìtílà náà nìyí: Wúrà tí wọ́n fi òòlù lù ni wọ́n fi ṣe é; òòlù ni wọ́n fi lù ú+ láti ibi ọ̀pá rẹ̀ débi àwọn ìtànná rẹ̀. Wọ́n ṣe ọ̀pá fìtílà náà bó ṣe rí nínú ìran+ tí Jèhófà fi han Mósè.
4 Bí wọ́n ṣe ṣe ọ̀pá fìtílà náà nìyí: Wúrà tí wọ́n fi òòlù lù ni wọ́n fi ṣe é; òòlù ni wọ́n fi lù ú+ láti ibi ọ̀pá rẹ̀ débi àwọn ìtànná rẹ̀. Wọ́n ṣe ọ̀pá fìtílà náà bó ṣe rí nínú ìran+ tí Jèhófà fi han Mósè.