Nọ́ńbà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kí wọ́n wá mú aṣọ aláwọ̀ búlúù, kí wọ́n sì fi bo ọ̀pá fìtílà+ tí wọ́n fi ń tan iná,+ pẹ̀lú àwọn fìtílà rẹ̀, àwọn ìpaná* rẹ̀, àwọn ìkóná rẹ̀+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ tí wọ́n ń fi òróró sí láti máa fi tàn án.
9 Kí wọ́n wá mú aṣọ aláwọ̀ búlúù, kí wọ́n sì fi bo ọ̀pá fìtílà+ tí wọ́n fi ń tan iná,+ pẹ̀lú àwọn fìtílà rẹ̀, àwọn ìpaná* rẹ̀, àwọn ìkóná rẹ̀+ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ tí wọ́n ń fi òróró sí láti máa fi tàn án.