-
Ẹ́kísódù 35:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Gbogbo àwọn obìnrin tó mọṣẹ́+ fi ọwọ́ wọn rànwú, wọ́n sì mú àwọn ohun tí wọ́n ṣe wá: fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa.
-