Lúùkù 20:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Àmọ́ tó bá kan àjíǹde àwọn òkú, Mósè pàápàá jẹ́ ká mọ̀ nínú ìtàn igi ẹlẹ́gùn-ún, nígbà tó pe Jèhófà* ní ‘Ọlọ́run Ábúráhámù, Ọlọ́run Ísákì àti Ọlọ́run Jékọ́bù.’+
37 Àmọ́ tó bá kan àjíǹde àwọn òkú, Mósè pàápàá jẹ́ ká mọ̀ nínú ìtàn igi ẹlẹ́gùn-ún, nígbà tó pe Jèhófà* ní ‘Ọlọ́run Ábúráhámù, Ọlọ́run Ísákì àti Ọlọ́run Jékọ́bù.’+