Léfítíkù 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Èyí ni ọrẹ tí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò mú wá fún Jèhófà ní ọjọ́ tí ẹ bá fòróró yàn wọ́n:+ ìyẹ̀fun tó kúnná tó jẹ́ ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà,*+ kí wọ́n máa fi ṣe ọrẹ ọkà+ nígbà gbogbo, ààbọ̀ rẹ̀ ní àárọ̀, ààbọ̀ rẹ̀ ní alẹ́.
20 “Èyí ni ọrẹ tí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò mú wá fún Jèhófà ní ọjọ́ tí ẹ bá fòróró yàn wọ́n:+ ìyẹ̀fun tó kúnná tó jẹ́ ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà,*+ kí wọ́n máa fi ṣe ọrẹ ọkà+ nígbà gbogbo, ààbọ̀ rẹ̀ ní àárọ̀, ààbọ̀ rẹ̀ ní alẹ́.