Léfítíkù 8:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mósè wá mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sún mọ́ tòsí, ó sì fi omi wẹ̀ wọ́n.+ Hébérù 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ẹ jẹ́ ká fi ọkàn tòótọ́ àti ìgbàgbọ́ tó kún rẹ́rẹ́ wá, nígbà tí a ti wẹ ọkàn wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀rí ọkàn burúkú,+ tí a sì ti fi omi tó mọ́ wẹ ara wa.+
22 ẹ jẹ́ ká fi ọkàn tòótọ́ àti ìgbàgbọ́ tó kún rẹ́rẹ́ wá, nígbà tí a ti wẹ ọkàn wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀rí ọkàn burúkú,+ tí a sì ti fi omi tó mọ́ wẹ ara wa.+