Léfítíkù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “‘Ó jẹ́ àṣẹ tó máa wà fún àwọn ìran yín títí lọ, ní gbogbo ibi tí ẹ̀ ń gbé: Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ọ̀rá tàbí ẹ̀jẹ̀+ èyíkéyìí.’”
17 “‘Ó jẹ́ àṣẹ tó máa wà fún àwọn ìran yín títí lọ, ní gbogbo ibi tí ẹ̀ ń gbé: Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ọ̀rá tàbí ẹ̀jẹ̀+ èyíkéyìí.’”