Ẹ́kísódù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ Mósè sọ fún Jèhófà pé: “Wò ó! Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò fetí sí mi;+ ṣé Fáráò ló máa wá fetí sí mi, èmi tí mi ò lè sọ̀rọ̀ dáadáa?”*+ Nọ́ńbà 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọkùnrin náà, Mósè, ló jẹ́ oníwà pẹ̀lẹ́ jù lọ nínú gbogbo èèyàn*+ tó wà láyé. Jeremáyà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ṣùgbọ́n mo sọ pé: “Áà, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ! Mi ò mọ ọ̀rọ̀ sọ,+ ọmọdé* lásán ni mí.”+ Ìṣe 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí náà, wọ́n kọ́ Mósè ní gbogbo ọgbọ́n àwọn ará Íjíbítì. Kódà, ó di alágbára ní ọ̀rọ̀ àti ní ìṣe.+
12 Àmọ́ Mósè sọ fún Jèhófà pé: “Wò ó! Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò fetí sí mi;+ ṣé Fáráò ló máa wá fetí sí mi, èmi tí mi ò lè sọ̀rọ̀ dáadáa?”*+
22 Nítorí náà, wọ́n kọ́ Mósè ní gbogbo ọgbọ́n àwọn ará Íjíbítì. Kódà, ó di alágbára ní ọ̀rọ̀ àti ní ìṣe.+