- 
	                        
            
            Jẹ́nẹ́sísì 47:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Jósẹ́fù wá mú kí bàbá rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ máa gbé ilẹ̀ náà, ó sì fún wọn ní ohun ìní nílẹ̀ Íjíbítì, níbi tó dáa jù ní ilẹ̀ náà, ní ilẹ̀ Rámésésì,+ bí Fáráò ṣe pàṣẹ. 
 
-